Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Riches: Heavenly treasures superior to

2 ẹsẹ · 107 abala

Wá "Riches"

Àwọn ẹsẹ nípa Heavenly treasures superior to

  1. “Má ṣe to àwọn ìṣúra jọ fún ara rẹ ní ayé yìí, níbi tí kòkòrò ti le jẹ ẹ́, tí ó sì ti le bàjẹ́ àti ibi tí àwọn olè lè fọ́ tí wọ́n yóò sì jí i lọ.

  2. Dípò bẹ́ẹ̀ to ìṣúra rẹ jọ sí ọ̀run, níbi ti kòkòrò àti ìpáàrà kò ti lè bà á jẹ́, àti ní ibi tí àwọn olè kò le fọ́ wọlé láti jí í lọ.