Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Reviling and Reproaching: Trust in God under

2 ẹsẹ · 35 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Trust in God under

  1. Òun yóò ránṣẹ́ láti ọ̀run wá, yóò sì gbà mí, bí ẹni tí ń fẹ́ gbé mi mì tilẹ̀ ń kẹ́gàn mi. Ọlọ́run yóò rán àánú rẹ̀ àti òdodo rẹ̀ jáde.

  2. Nígbà náà ni èmi yóò dá ẹni tí ń sọ̀rọ̀ ẹ̀gàn sí mi lóhùn, nítorí èmi gbẹ́kẹ̀lé ọ̀rọ̀ rẹ.