Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Reviling and Reproaching: Endure for Christ's sake
Àwọn ẹsẹ nípa Endure for Christ's sake
Alábùkún fún ni ẹ̀yin, nígbà tí àwọn ènìyàn bá kórìíra yín, tí wọ́n bá yà yín kúrò nínú ẹgbẹ́ wọn, tí wọ́n bá gàn yín, tí wọ́n bá ta orúkọ yín nù bí ohun búburú, nítorí Ọmọ Ènìyàn.