Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Reviling and Reproaching: Blessedness of enduring, for Christ's sake

2 ẹsẹ · 35 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Blessedness of enduring, for Christ's sake

  1. “Alábùkún fún ni ẹ̀yin nígbà tí àwọn ènìyàn bá fi àbùkù kàn yín tí wọn bá ṣe inúnibíni sí yín, tiwọn fi ètè èké sọ̀rọ̀ búburú gbogbo sí yín nítorí mi.

  2. Alábùkún fún ni ẹ̀yin, nígbà tí àwọn ènìyàn bá kórìíra yín, tí wọ́n bá yà yín kúrò nínú ẹgbẹ́ wọn, tí wọ́n bá gàn yín, tí wọ́n bá ta orúkọ yín nù bí ohun búburú, nítorí Ọmọ Ènìyàn.