Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Rebellion Against God: Restored through Christ alone
Àwọn ẹsẹ nípa Restored through Christ alone
Ìwọ ti gòkè sí ibi gíga ìwọ ti di ìgbèkùn ní ìgbèkùn lọ; ìwọ ti gba ẹ̀bùn fún ènìyàn: nítòótọ́, fún àwọn ọlọ̀tẹ̀ pẹ̀lú, kí Olúwa Ọlọ́run lè máa bá wọn gbé.