Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Rain: Causes the earth to open

2 ẹsẹ · 65 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Causes the earth to open

  1. Wọn a sì dúró dè mí bí ẹni wí pé wọ́n dúró fún ọ̀wọ́ òjò; wọn a sì mu nínú ọ̀rọ̀ mi bí ẹní mu nínú òjò àrọ̀kúrò.

  2. Ilẹ̀ náà sán nítorí pé kò sí òjò ní ilẹ̀ náà; ìrètí àwọn àgbẹ̀ di òfo, wọ́n sì bo orí wọn.