Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prophecies Respecting Christ: That a bone of him should not be broken
Àwọn ẹsẹ nípa That a bone of him should not be broken
“Nínú ilé ni ẹ ti gbọdọ̀ jẹ ẹ́; ẹ kò gbọdọ̀ mú èyíkéyìí nínú ẹran náà jáde kúrò nínú ilé. Ẹ má ṣe ṣẹ́ ọ̀kankan nínú egungun rẹ̀.
Ó pa gbogbo egungun wọn mọ́; kò sí ọ̀kan tí ó dá nínú wọn.