Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prophecies Respecting Christ: His being born a virgin
Àwọn ẹsẹ nípa His being born a virgin
Nítorí náà, Olúwa fúnra ara rẹ̀ ni yóò fún ọ ní àmì kan. Wúńdíá kan yóò lóyún, yóò sì bí ọmọkùnrin kan, yóò sì pe orúkọ rẹ̀ ní Emmanueli.