Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prophecies Respecting Christ: As the seed of Isaac
Àwọn ẹsẹ nípa As the seed of Isaac
Ṣùgbọ́n Ọlọ́run wí fun Abrahamu pé, “Má ṣe ba ọkàn jẹ́ nítorí ọmọ náà àti ẹrúbìnrin rẹ. Gbọ́ ohun tí Sara wí fún ọ, nítorí nínú Isaaki ni a ó ti pe irú-ọmọ rẹ̀.