Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Presents: In token of friendship

2 ẹsẹ · 37 abala

Àwọn ẹsẹ nípa In token of friendship

  1. Jonatani bá Dafidi dá májẹ̀mú nítorí tí ó fẹ́ràn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ara rẹ̀.

  2. Jonatani sì bọ́ aṣọ ìgúnwà, ó sì fi fun Dafidi pẹ̀lú aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ rẹ̀ àti pẹ̀lú idà rẹ̀, ọrun rẹ̀ àti àmùrè rẹ̀.