Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Presents: Considered essential on all visits of business
Àwọn ẹsẹ nípa Considered essential on all visits of business
Saulu sọ fún ìránṣẹ́ rẹ̀, “Tí àwa bá lọ, kín ni àwa lè fún ọkùnrin náà? Oúnjẹ inú àpò wa ti tán. A kò sì ní ẹ̀bùn láti mú lọ sọ́dọ̀ ènìyàn Ọlọ́run. Kí ni a ní?”