Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Presents: To kings to engage their aid

1 ẹsẹ · 37 abala

Àwọn ẹsẹ nípa To kings to engage their aid

  1. Nígbà náà ni Asa mú gbogbo fàdákà àti wúrà tí ó kù nínú ìṣúra ilé Olúwa àti ìṣúra ilé ọba. Ó sì fi lé àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ lọ́wọ́, ó sì rán wọn lọ sí ọ̀dọ̀ Beni-Hadadi ọmọ Tabrimoni, ọmọ Hesioni ọba Siria tí ó ń gbé ní Damasku.