Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Precious Stones: Carbuncle

2 ẹsẹ · 52 abala

Wá "Precious Stones"

Àwọn ẹsẹ nípa Carbuncle

  1. Nígbà náà ni ìwọ yóò de òkúta oníyebíye mẹ́rin sára ẹsẹ̀ rẹ̀. Ní ẹsẹ̀ àkọ́kọ́ ni kí rúbì, topasi àti berili wà;

  2. Èmi yóò fi iyùn ṣe odi rẹ, àwọn ẹnu-ọ̀nà ni a ó fi ohun èlò dáradára fún, àti àwọn ògiri rẹ pẹ̀lú òkúta iyebíye.