Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Precious Stones: Adorning the high priest's ephod
Àwọn ẹsẹ nípa Adorning the high priest's ephod
Ìwọ yóò sì so wọ́n pọ̀ mọ́ èjìká efodu náà ní òkúta ìrántí fún àwọn ọmọ Israẹli. Aaroni yóò sì máa ní orúkọ wọn níwájú Olúwa ní èjìká rẹ̀ méjèèjì fún ìrántí.