Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Precious Stones: Sardine or Sardius

2 ẹsẹ · 52 abala

Wá "Precious Stones"

Àwọn ẹsẹ nípa Sardine or Sardius

  1. Nígbà náà ni ìwọ yóò de òkúta oníyebíye mẹ́rin sára ẹsẹ̀ rẹ̀. Ní ẹsẹ̀ àkọ́kọ́ ni kí rúbì, topasi àti berili wà;

  2. Ẹni tí ó sì jókòó náà dàbí òkúta jasperi àti kaneliani lójú. Ni àyíká ìtẹ́ náà ni òṣùmàrè kan wà tí ó dàbí òkúta emeradi lójú.