Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Patriarchal Government: Acting as judges
Àwọn ẹsẹ nípa Acting as judges
Lẹ́yìn nǹkan bí oṣù mẹ́ta, wọn sọ fún Juda pé, “Tamari aya ọmọ rẹ̀ ṣe àgbèrè, ó sì ti lóyún.” Juda sì wí pé, “Ẹ mú un jáde, kí ẹ sì dá iná sun ún.”