Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Morning: The second part of the day at the creation

6 ẹsẹ · 27 abala

Àwọn ẹsẹ nípa The second part of the day at the creation

  1. Ọlọ́run sì pe ìmọ́lẹ̀ náà ní “ọ̀sán,” àti òkùnkùn ní “òru.” Àṣálẹ́ àti òwúrọ̀ sì jẹ́ ọjọ́ kìn-ín-ní.

  2. Ọlọ́run sì pe òfúrufú ní “ọ̀run.” Àṣálẹ́ àti òwúrọ̀ sì jẹ́ ọjọ́ kejì.

  3. Àṣálẹ́ àti òwúrọ̀ sì jẹ́ ọjọ́ kẹta.

  4. Àṣálẹ́ àti òwúrọ̀ sì jẹ́ ọjọ́ kẹrin.

  5. Àṣálẹ́ àti òwúrọ̀ sì jẹ́ ọjọ́ karùn-ún.

  6. Ọlọ́run sì rí àwọn ohun gbogbo tí ó dá, ó dára gidigidi. Àṣálẹ́ àti òwúrọ̀ sì jẹ́ ọjọ́ kẹfà.