Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Missionary Work By Ministers: A cause of joy
Àwọn ẹsẹ nípa A cause of joy
Nítorí náà, bí ìjọ ti rán wọn jáde lọ sí ọ̀nà wọn, wọn la Fonisia àti Samaria kọjá, wọ́n ń ròyìn ìyípadà àwọn aláìkọlà, wọ́n sì fi ayọ̀ ńlá fún gbogbo àwọn arákùnrin.