Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Missionary Work By Ministers: Timotheus
Àwọn ẹsẹ nípa Timotheus
Òun ni Paulu fẹ́ kí ó bá òun lọ; ó sì mú un, ó sì kọ ọ́ ní ilà, nítorí àwọn Júù tí ó wà ní agbègbè wọ̀nyí, nítorí gbogbo wọn mọ̀ pé, Giriki ni baba rẹ̀.