Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Miracles Through Evil Agents: By false christs
Àwọn ẹsẹ nípa By false christs
Nítorí àwọn èké Kristi àti àwọn èké wòlíì yóò dìde. Wọn yóò sì ṣe ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àmì àti ìyanu. Bí ó bá lè ṣe é ṣe wọn yóò tan àwọn àyànfẹ́ Ọlọ́run pàápàá jẹ.