Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Miracles Through Evil Agents: Not to be regarded
Àwọn ẹsẹ nípa Not to be regarded
ẹ má fetí sí ọ̀rọ̀ wòlíì tàbí àlá náà, Olúwa Ọlọ́run yín ń dán an yín wò ni, láti mọ̀ bóyá ẹ fẹ́ràn rẹ̀ pẹ̀lú gbogbo àyà yín àti gbogbo ọkàn an yín.