Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Judgments: Upon Hananiah, the false prophet
Àwọn ẹsẹ nípa Upon Hananiah, the false prophet
Wòlíì Jeremiah sọ fún wòlíì Hananiah pé, “Gbọ́ ọ, Hananiah! Olúwa kò rán ọ, síbẹ̀, ìwọ jẹ́ kí orílẹ̀-èdè yìí gba irọ́ gbọ́.
Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa wí: ‘Mo ṣetán láti mú ọ kúrò nínú ayé, ní ọdún yìí ni ìwọ yóò kú nítorí o ti wàásù ọ̀tẹ̀ sí Olúwa.’ ”
Ní oṣù keje ọdún yìí ni Hananiah wòlíì kú.