Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Judges of Israel: Jair

3 ẹsẹ · 17 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Jair

  1. Jairi ti ẹ̀yà Gileadi ni ó dìde lẹ́yìn rẹ̀, ó ṣàkóso Israẹli ní ọdún méjìlélógún.

  2. Àwọn ọgbọ̀n ọmọ tí ó n gun ọgbọ̀n kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́. Wọ́n ṣe àkóso ọgbọ̀n ìlú ní Gileadi, tí a pe orúkọ wọn ní Hafoti-Jairi títí di òní.

  3. Nígbà tí Jairi kú wọ́n sin ín sí Kamoni.