Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Intercessory Prayer: Ezekiel

1 ẹsẹ · 43 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Ezekiel

  1. Èmi nìkan ló ṣẹ́kù nígbà tí wọ́n lọ pa àwọn ènìyàn, mo dójú mi bolẹ̀, mo kígbe pé, “Háà! Olúwa Olódùmarè! Ìwọ yóò ha pa ìyókù Israẹli nípa dída ìbínú gbígbóná rẹ sórí Jerusalẹmu?”