Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Intercessory Prayer: Beneficial to the offerer
Àwọn ẹsẹ nípa Beneficial to the offerer
Olúwa sì yí ìgbèkùn Jobu padà, nígbà tí ó gbàdúrà fún àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀; Olúwa sì bùsi ohun gbogbo ti Jobu ní rí ní ìṣẹ́po méjì ohun tí ó ní tẹ́lẹ̀ rí.