Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa False Prophets: Often deceived by God as a judgment
Àwọn ẹsẹ nípa Often deceived by God as a judgment
“ ‘Bí wọ́n bá sì tan wòlíì náà láti sọtẹ́lẹ̀, Èmi Olúwa ló tan wòlíì náà, Èmi yóò nawọ́ sí i, èmi yóò sì pa á run kúrò láàrín àwọn ènìyàn mi Israẹli.