Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa False Prophets: Lies in the name of the Lord

1 ẹsẹ · 33 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Lies in the name of the Lord

  1. Nígbà náà Olúwa sọ fún mi pé, “Àwọn wòlíì ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ èké ní orúkọ mi. Èmi kò rán wọn, tàbí yàn wọ́n tàbí bá wọn sọ̀rọ̀. Ìran èké ni wọ́n ń rí sí i yín. Àsọtẹ́lẹ̀ èké ni wọ́n ń sọ fún un yín nípa ìran ìrírí, àfọ̀ṣẹ, ìbọ̀rìṣà àti ìtànjẹ ọkàn wọn.