Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Assyria: Antiquity and origin of
Àwọn ẹsẹ nípa Antiquity and origin of
Kuṣi sì bí Nimrodu, ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé.
Ó sì jẹ́ ògbójú ọdẹ níwájú Olúwa; nítorí náà ni a ṣe ń wí pé, “Bí Nimrodu, ògbójú ọdẹ níwájú Olúwa.”
Ìjọba rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ ni Babeli, Ereki, Akkadi, Kalne, gbogbo wọn wà ní ilẹ̀ Ṣinari.
Láti ilẹ̀ náà ni ó ti lọ sí Asiria, níbi tí ó ti tẹ ìlú Ninefe, Rehoboti àti Kala,