Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prayer Under Affliction: For the presence and support of God

2 ẹsẹ · 17 abala

Àwọn ẹsẹ nípa For the presence and support of God

  1. Èéha ti ṣe, Olúwa, tí ìwọ fi dúró ní òkè réré? Èéha ti ṣe, tí ìwọ fi ara rẹ pamọ́ ní ìgbà ìpọ́njú?

  2. Má ṣe pa ojú rẹ mọ́ kúrò lọ́dọ̀ mi ní ọjọ́ tí èmi wà nínú ìpọ́njú. Dẹ etí rẹ sí mi; nígbà tí mo bá pè, dá mi lóhùn kíákíá.