Fò sí àkóónú
Saamu 29:10-11

Ìjọba Ọlọ́run ayérayé àti ìbùkún

Saamu 29:10-11
10
Olúwa jókòó, Ó sì jẹ ọba lórí ìṣàn omi; Olúwa jókòó lórí ìtẹ́ gẹ́gẹ́ bí Ọba títí láéláé.
11
Kí Olúwa fi agbára fún àwọn ènìyàn rẹ̀; bùkún àwọn ènìyàn rẹ̀ pẹ̀lú àlàáfíà.
Settings

Reading Style

Typeface

Font Size 19px

Reading Width 45 chars

Options