Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Walls: The falling of, sometimes occasioned great destruction
Àwọn ẹsẹ nípa The falling of, sometimes occasioned great destruction
Àwọn tókù sì sá àsálà lọ sí Afeki, sínú ìlú tí odi ti wó lù ẹgbàá mẹ́tàlá lé ẹgbẹ̀rún (27,000) nínú wọn. Beni-Hadadi sì sálọ sínú ìlú, ó sì fi ara pamọ́ sínú ìyẹ̀wù.