Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Walls: Small towns and villages were not surrounded by

2 ẹsẹ · 48 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Small towns and villages were not surrounded by

  1. Ṣùgbọ́n àwọn ilé tí ó wà ní abúlé láìní odi ni kí a kà gẹ́gẹ́ bí ilẹ̀ oko, a lè rà wọ́n padà, kí wọ́n sì da padà ní ọdún ìdásílẹ̀.

  2. Gbogbo ìlú wọ̀nyí ní a mọ odi gíga yíká pẹ̀lú àwọn ìlẹ̀kùn àti irin. Ọ̀pọ̀ àwọn ìlú kéékèèké tí a kò mọ odi yíká sì tún wà pẹ̀lú.