Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Walls: Strongly fortified
Àwọn ẹsẹ nípa Strongly fortified
fún ilé ìṣọ́ gíga gíga àti àwọn odi ìdáàbòbò,
Òun yóò sì bi gbogbo ògiri gíga alágbára yín lulẹ̀ wọn yóò sì wà nílẹ̀, Òun yóò sì mú wọn wá si ilẹ̀, àní sí erùpẹ̀ lásán.