Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Unity of God: Consistent with the deity of Christ and of the Holy Spirit

5 ẹsẹ · 20 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Consistent with the deity of Christ and of the Holy Spirit

  1. Ọ̀kan ni èmi àti Baba mi.”

  2. Jesu wí fún un pé, “Bí àkókò tí mo bá yín gbé ti tó yìí, ìwọ, kò sì tí ì mọ̀ mí síbẹ̀ Filipi? Ẹni tí ó bá ti rí mi, ó ti rí Baba. Ìwọ ha ti ṣe wí pé, ‘Fi Baba hàn wá!’

  3. Ìwọ kò ha gbàgbọ́ pé, èmi wà nínú Baba, àti pé Baba wà nínú mi? Ọ̀rọ̀ tí èmi ń sọ fún yín, èmi kò dá a sọ; ṣùgbọ́n Baba ti ó wà nínú mi, òun ní ń ṣe iṣẹ́ rẹ̀.

  4. Ẹ gbà mí gbọ́ pé, èmi wà nínú Baba, Baba sì wà nínú mi, bí kò ṣe bẹ́ẹ̀, ẹ gbà mí gbọ́ nítorí àwọn ẹ̀rí iṣẹ́ náà pàápàá!

  5. Nítorí pé àwọn mẹ́ta ni ó ń jẹ́rìí.