Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Union With Christ: Enjoy, in the Lord's supper

2 ẹsẹ · 41 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Enjoy, in the Lord's supper

  1. Ǹjẹ́ ago ìdúpẹ́ nípasẹ̀ èyí tí a ń dúpẹ́ fún, kì í ha ṣe jíjẹ́ alábápín ìdàpọ̀ nínú ẹ̀jẹ̀ Kristi bí? Àkàrà tí a bù, kì í ha ṣe jíjẹ́ alábápín nínú ara Kristi bi?

  2. Nítorí àkàrà kan ni ó ń bẹ, àwa tí a pọ̀ níye, tí a sì jẹ ara kan ń pín nínú àkàrà kan ṣoṣo.