Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Union With Christ: Abundant fruitfulness
Àwọn ẹsẹ nípa Abundant fruitfulness
“Èmi ni àjàrà, ẹ̀yin ni ẹ̀ka. Ẹni tí ó ń gbé inú mi, àti èmi nínú rẹ̀, òun ni yóò so èso lọ́pọ̀lọ́pọ̀, nítorí ní yíya ara yín kúrò lọ́dọ̀ mi, ẹ kò lè ṣe ohun kan.