Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Union With Christ: Confidence at his coming
Àwọn ẹsẹ nípa Confidence at his coming
Àti nísinsin yìí, ẹ̀yin ọmọ mi ọ̀wọ́n, ẹ máa gbé inú rẹ̀, pé nígbà tí òun ó bá farahàn, kí a lè ni ìgboyà níwájú rẹ̀, kí ojú má sì tì wá níwájú rẹ̀ ni ìgbà wíwá rẹ̀.