Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Trust: In the mercy of God

2 ẹsẹ · 66 abala

Àwọn ẹsẹ nípa In the mercy of God

  1. Ṣùgbọ́n mo gbẹ́kẹ̀lé ìfẹ́ rẹ tí kì í kùnà; ọkàn mi ń yọ̀ nínú ìgbàlà rẹ.

  2. Ṣùgbọ́n èmi dàbí igi Olifi tí ó gbilẹ̀ nínú ilé Ọlọ́run; èmi gbẹ́kẹ̀lé ìfẹ́ Ọlọ́run tí kì í kùnà láé àti láéláé.