Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Trust: Being compassed with mercy
Àwọn ẹsẹ nípa Being compassed with mercy
Ọ̀pọ̀ ìkáàánú ní yóò wà fún ènìyàn búburú, ṣùgbọ́n ìfẹ́ Olúwa tí ó dúró ṣinṣin ni yóò yí àwọn tí ó ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú Olúwa ká.