Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Trumpet: The war-horse acquainted with the sound of
Àwọn ẹsẹ nípa The war-horse acquainted with the sound of
Ó fi kíkorò ojú àti ìbínú ńlá gbé ilé mi, bẹ́ẹ̀ ni òun kò sì gbà á gbọ́ pé, ìró ìpè ni.
Ó wí nígbà ìpè pé, Háà! Háà! Ó sì gbóhùn ogun lókèèrè réré, igbe àwọn balógun àti ìhó ayọ̀ ogun wọn.