Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Trumpet: Used on the great day of atonement
Àwọn ẹsẹ nípa Used on the great day of atonement
Àti ní ọjọ́ náà, a ó fun fèrè ńlá kan. Gbogbo àwọn tí ń ṣègbé lọ ní Asiria àti àwọn tí ń ṣe àtìpó ní Ejibiti yóò wá sin Olúwa ní òkè mímọ́ ní Jerusalẹmu.