Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tribute: Persons enroled for, in the native place of their tribe and family

3 ẹsẹ · 24 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Persons enroled for, in the native place of their tribe and family

  1. Gbogbo àwọn ènìyàn sì lọ láti kọ orúkọ wọn sínú ìwé, olúkúlùkù sí ìlú ara rẹ̀.

  2. Josẹfu pẹ̀lú sì gòkè láti Nasareti ni Galili, sí ìlú Dafidi ní Judea, tí à ń pè ní Bẹtilẹhẹmu; nítorí ti ìran àti ìdílé Dafidi ní í ṣe,

  3. láti kọ orúkọ rẹ̀, pẹ̀lú Maria aya rẹ̀ àfẹ́sọ́nà, tí oyún rẹ̀ ti tó bí.