Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tribute: Produce of land, &c

2 ẹsẹ · 24 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Produce of land, &c

  1. Yóò mú ìdásímẹ́wàá hóró ọkà yín àti àká èso àjàrà yín, yóò sì fi fún àwọn oníṣẹ́ àti ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀.

  2. Solomoni sì tún ní ìjòyè méjìlá lórí gbogbo agbègbè Israẹli, tí wọ́n ń pèsè oúnjẹ fún ọba àti agbo ilé rẹ̀. Olúkúlùkù ní láti pèsè fún oṣù kan ní ọdún.