Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tribute: By Arabians to Solomon
Àwọn ẹsẹ nípa By Arabians to Solomon
láì tí ì ka àkójọpọ̀ owó ìlú tí ó wọlé láti ọ̀dọ̀ àwọn oníṣòwò àti àwọn ọlọ́jà. Àti pẹ̀lú gbogbo àwọn ọba Arabia àti àwọn baálẹ̀ ilẹ̀ náà mu wúrà àti fàdákà wá fún Solomoni.