Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Theft: Brings the wrath of God upon those who commit it

2 ẹsẹ · 34 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Brings the wrath of God upon those who commit it

  1. Àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà, tí lo ìwà ìninilára, wọn sì já olè, wọn sì ni àwọn tálákà àti aláìní lára; nítòótọ́, wọn tí ní àlejò lára láìnídìí. Kò sì ṣí ìdájọ́ òdodo.

  2. Nítorí náà ni mo ṣe da ìbínú mi sí wọn lórí, mo ti fi iná ìbínú mi run wọn, mo si ti fi ọ̀nà wọn gbẹ̀san lórí ara wọn, ní Olúwa Olódùmarè wí.”