Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Theft: Associate with those who commit

1 ẹsẹ · 34 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Associate with those who commit

  1. Ọlọ̀tẹ̀ ni àwọn aláṣẹ yín, akẹgbẹ́ àwọn olè, gbogbo wọn ló fẹ́ràn àbẹ̀tẹ́lẹ̀ wọ́n sì ń wá ẹ̀bùn kiri. Wọ́n kì í ṣàtìlẹyìn fún ẹ̀tọ́ aláìní baba, ẹjọ́ opó kì í sì í dé iwájú wọn.