Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Wind: Quails brought by

1 ẹsẹ · 55 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Quails brought by

  1. Afẹ́fẹ́ sì jáde láti ọ̀dọ̀ Olúwa ó sì kó àparò wá láti inú Òkun. Ó sì dà wọ́n káàkiri gbogbo ibùdó ní ìwọ̀n gíga ẹsẹ̀ bàtà mẹ́ta sórí ilẹ̀, bí ìwọ̀n ìrìn ọjọ́ kan ní gbogbo àyíká.