Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Wind: (Feeding upon) of vain hopes
Àwọn ẹsẹ nípa (Feeding upon) of vain hopes
Efraimu ń jẹ afẹ́fẹ́; o ń lépa afẹ́fẹ́ ìwọ̀-oòrùn ní gbogbo ọjọ́. O sì ń gbèrú nínú irọ́ o dá májẹ̀mú pẹ̀lú Asiria o sì fi òróró olifi ránṣẹ́ sí Ejibiti.