Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Second Coming of Christ: In the glory of his Father
Àwọn ẹsẹ nípa In the glory of his Father
Nítorí Ọmọ Ènìyàn yóò wá nínú ògo baba rẹ pẹ̀lú àwọn angẹli rẹ̀, nígbà náà ni yóò sì san án fún olúkúlùkù gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀.