Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Second Coming of Christ: Every eye shall see him at
Àwọn ẹsẹ nípa Every eye shall see him at
“Kíyèsi i, o ń bọ̀ nínú àwọsánmọ̀, gbogbo ojú ni yóò sì rí i, àti àwọn tí ó gún un ní ọ̀kọ̀ pẹ̀lú”; àti gbogbo orílẹ̀-èdè ayé ni “yóò sì máa pohùnréré ẹkún nítorí rẹ̀.”